O. Daf 120:5-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Egbe ni fun mi, ti mo ṣe atipo ni Meṣeki, ti mo joko ninu agọ Kedari!

6. O ti pẹ ti ọkàn mi ti ba ẹniti o korira alafia gbe.

7. Alafia ni mo fẹ: ṣugbọn nigbati mo ba sọ̀rọ, ija ni ti wọn.

O. Daf 120