O. Daf 12:7-8 Yorùbá Bibeli (YCE)

7. Iwọ o pa wọn mọ́, Oluwa, iwọ o pa olukuluku wọn mọ́ kuro lọwọ iran yi lailai.

8. Awọn enia buburu nrìn ni iha gbogbo, nigbati a ba gbé awọn enia-kenia leke.

O. Daf 12