O. Daf 119:3-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Nwọn kò dẹṣẹ pẹlu: nwọn nrìn li ọ̀na rẹ̀.

4. Iwọ ti paṣẹ fun wa lati pa ẹkọ́ rẹ mọ́ gidigidi.

5. Ọ̀na mi iba jẹ là silẹ lati ma pa ilana rẹ mọ́!

6. Nigbana li oju kì yio tì mi, nigbati emi ba njuba aṣẹ rẹ gbogbo.

7. Emi o ma fi aiya diduro-ṣinṣin yìn ọ, nigbati emi ba ti kọ́ idajọ ododo rẹ.

O. Daf 119