O. Daf 119:12-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Olubukún ni iwọ, Oluwa: kọ́ mi ni ilana rẹ.

13. Ẹnu mi li emi fi nsọ gbogbo idajọ ẹnu rẹ.

14. Emi ti nyọ̀ li ọ̀na ẹri rẹ, bi lori oniruru ọrọ̀.

15. Emi o ma ṣe àṣaro ninu ẹkọ́ rẹ emi o si ma juba ọ̀na rẹ.

O. Daf 119