O. Daf 110:6-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Yio ṣe idajọ lãrin awọn keferi, yio fi okú kún ibi wọnni; yio fọ́ ori lori ilẹ pupọ̀.

7. Yio ma mu ninu odò na li ọ̀na: nitorina ni yio ṣe gbé ori soke.

O. Daf 110