O. Daf 109:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ti fẹ egun, bẹ̃ni ki o de si i: bi inu rẹ̀ kò ti dùn si ire, bẹ̃ni ki o jina si i.

O. Daf 109

O. Daf 109:14-24