O. Daf 107:33-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. O sọ odò di aginju, ati orisun omi di ilẹ gbigbẹ;

34. Ilẹ eleso di aṣálẹ̀, nitori ìwa-buburu awọn ti o wà ninu rẹ̀.

35. O sọ aginju di adagun omi, ati ilẹ gbigbẹ di orisun omi.

36. Nibẹ li o si mu awọn ti ebi npa joko, ki nwọn ki o le tẹ ilu do, lati ma gbe.

O. Daf 107