O. Daf 107:31-34 Yorùbá Bibeli (YCE)

31. Enia iba ma yìn Oluwa nitori ore rẹ̀, ati nitori iṣẹ iyanu rẹ̀ si awọn ọmọ enia!

32. Ki nwọn ki o gbé e ga pẹlu ni ijọ enia, ki nwọn ki o si yìn i ninu ijọ awọn àgba.

33. O sọ odò di aginju, ati orisun omi di ilẹ gbigbẹ;

34. Ilẹ eleso di aṣálẹ̀, nitori ìwa-buburu awọn ti o wà ninu rẹ̀.

O. Daf 107