O. Daf 106:16-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Nwọn ṣe ilara Mose pẹlu ni ibudo, ati Aaroni, ẹni-mimọ́ Oluwa.

17. Ilẹ là, o si gbé Datani mì, o si bò ẹgbẹ́ Abiramu mọlẹ.

18. Iná si ràn li ẹgbẹ́ wọn; ọwọ́ iná na jó awọn enia buburu.

O. Daf 106