O. Daf 105:44-45 Yorùbá Bibeli (YCE)

44. O si fi ilẹ awọn keferi fun wọn: nwọn si jogun ère iṣẹ awọn enia na.

45. Ki nwọn ki o le ma kiye si aṣẹ rẹ̀, ki nwọn ki o si ma pa ofin rẹ̀ mọ́. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.

O. Daf 105