O. Daf 105:39-41 Yorùbá Bibeli (YCE)

39. O nà awọsanma kan fun ibori; ati iná lati fun wọn ni imọlẹ li oru.

40. Nwọn bère o si mu ẹiyẹ aparo wá, o si fi onjẹ ọrun tẹ wọn lọrun.

41. O là apata, omi si tú jade; odò nṣan nibi gbigbẹ.

O. Daf 105