O. Daf 105:18-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Ẹsẹ ẹniti nwọn fi ṣẹkẹṣẹkẹ pa lara: a dè e ninu irin:

19. Titi igba ti ọ̀rọ rẹ̀ de: ọ̀rọ Oluwa dan a wò.

20. Ọba ranṣẹ, nwọn si tú u silẹ; ani ijoye awọn enia, o si jọwọ rẹ̀ lọwọ lọ.

21. O fi jẹ oluwa ile rẹ̀, ati ijoye gbogbo ini rẹ̀.

O. Daf 105