O. Daf 102:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Máṣe pa oju rẹ mọ́ kuro lara mi li ọjọ ti emi wà ninu ipọnju; dẹ eti rẹ si mi: li ọjọ ti mo ba pè, da mi lohùn-lọgan.

O. Daf 102

O. Daf 102:1-8