O. Daf 102:11-13 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. Ọjọ mi dabi ojiji ti o nfà sẹhin; emi si nrọ bi koriko.

12. Ṣugbọn iwọ, Oluwa, ni yio duro lailai; ati iranti rẹ lati iran dé iran.

13. Iwọ o dide, iwọ o ṣãnu fun Sioni: nitori igba ati ṣe oju-rere si i, nitõtọ, àkoko na de.

O. Daf 102