O. Daf 100:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹ ho iho ayọ̀ si Oluwa, ẹnyin ilẹ gbogbo.

2. Ẹ fi ayọ̀ sìn Oluwa: ẹ wá ti ẹnyin ti orin si iwaju rẹ̀.

3. Ki ẹnyin ki o mọ̀ pe Oluwa, on li Ọlọrun: on li o dá wa, tirẹ̀ li awa; awa li enia rẹ̀, ati agutan papa rẹ̀.

O. Daf 100