O. Daf 10:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enia buburu, nipa igberaga oju rẹ̀, kò fẹ ṣe afẹri Ọlọrun: Ọlọrun kò si ni gbogbo ironu rẹ̀.

O. Daf 10

O. Daf 10:1-8