Num 7:27-29 Yorùbá Bibeli (YCE)

27. Ẹgbọrọ akọmalu kan, àgbo kan, akọ ọdọ-agutan kan ọlọdún kan, fun ẹbọ sisun;

28. Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;

29. Ati fun ẹbọ ti ẹbọ alafia, akọmalu meji, àgbo marun, obukọ marun, akọ ọdọ-agutan marun ọlọdún kan: eyi li ọrẹ-ẹbọ ti Eliabu ọmọ Heloni.

Num 7