Num 7:26-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Ṣibi kan ìwọn ṣekeli mẹwa wurà, o kún fun turari;

27. Ẹgbọrọ akọmalu kan, àgbo kan, akọ ọdọ-agutan kan ọlọdún kan, fun ẹbọ sisun;

28. Akọ ewurẹ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ;

Num 7