Num 23:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú u wá si igbẹ Sofimu sori òke Pisga, o si mọ pẹpẹ meje, o si fi akọmalu kan ati àgbo kan rubọ lori pẹpẹ kọkan.

Num 23

Num 23:11-16