Num 1:6-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Ti Simeoni; Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai.

7. Ti Juda; Naṣoni ọmọ Amminadabu.

8. Ti Issakari; Netaneli ọmọ Suari.

9. Ti Sebuluni; Eliabu ọmọ Heloni.

10. Ti awọn ọmọ Josefu: ti Efraimu; Elliṣama ọmọ Ammihudu: ti Manasse; Gamalieli ọmọ Pedasuru.

Num 1