Neh 7:18-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Awọn ọmọ Adonikamu ọtalelẹgbẹta o le meje.

19. Awọn ọmọ Bigfai, ẹgbã o le mẹtadilãdọrin.

20. Awọn ọmọ Adini, ãdọtalelẹgbẹta o le marun.

21. Awọn ọmọ Ateri, ti Hesekiah mejidilọgọrun.

22. Awọn ọmọ Haṣamu, ọrindinirinwo o le mẹjọ.

Neh 7