Neh 12:14-23 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Ti Meliku, Jonatani; ti Ṣebaniah, Josefu;

15. Ti Harimu, Adna; ti Meraioti, Helkai;

16. Ti Iddo, Sekariah; ti Ginnetoni, Meṣullamu;

17. Ti Abijah, Sikri; ti Miniamini, ti Moadiah, Piltai:

18. Ti Bilga, Sammua; ti Ṣemaiah, Jehonatani;

19. Ati ti Joaribu, Mattenai; ti Jedaiah, Ussi;

20. Ti Sallai, Killai; ti Amoku, Eberi;

21. Ti Hilkiah, Haṣhabiah; ti Jedaiah, Netaneeli;

22. Ninu awọn ọmọ Lefi li ọjọ Eliaṣibu, Joiada, ati Johanani, ati Jaddua, awọn olori awọn baba: li a kọ sinu iwe pẹlu awọn alufa, titi di ijọba Dariusi ara Perṣia.

23. Awọn ọmọ Lefi, olori awọn baba li a kọ sinu iwe itan titi di ọjọ Johanani ọmọ Eliaṣibu.

Neh 12