Mat 26:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ mã ṣọna, ki ẹ si mã gbadura, ki ẹnyin ki o má ba bọ sinu idẹwò: lõtọ li ẹmi nfẹ ṣugbọn o ṣe alailera fun ara.

Mat 26

Mat 26:31-45