Mat 22:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Jesu si dahùn, o si tún fi owe sọ̀rọ fun wọn pe,

2. Ijọba ọrun dabi ọba kan, ti o ṣe igbeyawo fun ọmọ rẹ̀.

3. O si rán awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ lọ ipè awọn ti a ti pè tẹlẹ si ibi iyawo: ṣugbọn nwọn kò fẹ wá.

Mat 22