Mal 2:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ofin otitọ wà li ẹnu rẹ̀, a kò si ri ìwa-buburu li etè rẹ̀: o ba mi rìn li alafia ati ni ododo, o si yi ọ̀pọlọpọ kuro ninu ìwa-buburu.

Mal 2

Mal 2:1-13