Mak 13:36-37 Yorùbá Bibeli (YCE)

36. Pe, nigbati o ba de li ojijì, ki o máṣe ba nyin li oju orun.

37. Ohun ti mo wi fun nyin, mo wi fun gbogbo enia, Ẹ mã ṣọna.

Mak 13