Mak 10:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si wò wọn o wipe, Enia li eyi ko le ṣe iṣe fun, ṣugbọn ki iṣe fun Ọlọrun: nitori ohun gbogbo ni ṣiṣe fun Ọlọrun.

Mak 10

Mak 10:24-32