Mak 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnu si yà wọn si ẹkọ́ rẹ̀: nitoriti o nkọ́ wọn bi ẹniti o li aṣẹ, kì isi ṣe bí awọn akọwe.

Mak 1

Mak 1:12-32