Luk 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Èṣu si wi fun u pe, Iwọ li emi o fi gbogbo agbara yi ati ogo wọn fun: gbogbo rẹ̀ li a sá ti fifun mi; ẹnikẹni ti o ba si wù mi, emi a fi i fun.

Luk 4

Luk 4:3-10