Luk 21:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọrun on aiye yio rekọja: ṣugbọn ọ̀rọ mi kì yio rekọja.

Luk 21

Luk 21:26-38