Luk 20:38-41 Yorùbá Bibeli (YCE)

38. Bẹni on kì iṣe Ọlọrun awọn okú, bikoṣe ti awọn alãye: nitori gbogbo wọn wà lãye fun u.

39. Nigbana li awọn kan ninu awọn akọwe da a lohùn, wipe, Olukọni iwọ wi rere.

40. Nwọn kò si jẹ bi i lẽre òrọ kan mọ́.

41. O si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti nwọn fi nwipe, Ọmọ Dafidi ni Kristi?

Luk 20