Luk 15:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati ọmọ rẹ yi de, ẹniti o fi panṣaga run ọrọ̀ rẹ, iwọ si ti pa ẹgbọ̀rọ malu abọpa fun u.

Luk 15

Luk 15:26-32