Lef 19:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ kò gbọdọ bú aditi, tabi ki o fi ohun idugbolu siwaju afọju, ṣugbọn ki iwọ ki o bẹ̀ru Ọlọrun rẹ: Emi li OLUWA.

Lef 19

Lef 19:5-17