Lef 13:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn li oju rẹ̀ bi pipa na ba duro, ti irun dudu si hù ninu rẹ̀; pipa na jiná, mimọ́ li on: ki alufa ki o pè e ni mimọ́.

Lef 13

Lef 13:28-43