Joh 8:58-59 Yorùbá Bibeli (YCE)

58. Jesu si wi fun wọn pe, Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin, Ki Abrahamu to wà, emi ti wà.

59. Nitorina nwọn gbé okuta lati sọ lù u: ṣugbọn Jesu fi ara rẹ̀ pamọ́, o si jade kuro ni tẹmpili.

Joh 8