Joh 5:32-34 Yorùbá Bibeli (YCE)

32. Ẹlomiran li ẹniti njẹri mi; emi si mọ̀ pe, otitọ li ẹrí mi ti o jẹ́.

33. Ẹnyin ti ranṣẹ lọ sọdọ Johanu, on si ti jẹri si otitọ.

34. Ṣugbọn emi kò gba ẹrí lọdọ enia: ṣugbọn nkan wọnyi li emi nsọ, ki ẹnyin ki o le là.

Joh 5