Joh 21:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Simoni Peteru gòke, o si fà àwọn na wálẹ, o kún fun ẹja nla, o jẹ mẹtalelãdọjọ: bi nwọn si ti pọ̀ to nì, àwọn na kò ya.

Joh 21

Joh 21:5-14