Joh 16:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NKAN wọnyi ni mo ti sọ fun nyin, ki a má ba mu nyin kọsẹ̀.

2. Nwọn o yọ nyin kuro ninu sinagogu: ani, akokò mbọ̀, ti ẹnikẹni ti o ba pa nyin, yio rò pe on nṣe ìsin fun Ọlọrun.

Joh 16