Joh 15:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. EMI ni àjara tõtọ, Baba mi si ni oluṣọgba.

2. Gbogbo ẹká ninu mi ti kò ba so eso, on a mu u kuro: gbogbo ẹka ti o ba si so eso, on a wẹ̀ ẹ mọ́, ki o le so eso si i.

3. Ẹnyin mọ́ nisisiyi nitori ọ̀rọ ti mo ti sọ fun nyin.

Joh 15