Joh 12:44-46 Yorùbá Bibeli (YCE)

44. Jesu si kigbe o si wipe, Ẹniti o ba gbà mi gbọ́, emi kọ li o gbàgbọ́, ṣugbọn ẹniti o rán mi.

45. Ẹniti o ba si ri mi, o ri ẹniti o rán mi.

46. Emi ni imọlẹ ti o wá si aiye, ki ẹnikẹni ti o ba gbà mi gbọ́ ki o máṣe wà li òkunkun.

Joh 12