Joh 11:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iṣe fun ara rẹ̀ li o sọ eyi: ṣugbọn bi o ti jẹ olori alufa li ọdún na, o sọtẹlẹ pe, Jesu yio kú fun orilẹ-ède na:

Joh 11

Joh 11:41-57