Joh 11:18-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Njẹ Betani sunmọ Jerusalemu to furlongi mẹdogun:

19. Ọ̀pọ ninu awọn Ju si wá sọdọ Marta ati Maria, lati tù wọn ninu nitori ti arakunrin wọn.

20. Nitorina nigbati Marta gbọ́ pe Jesu mbọ̀ wá, o jade lọ ipade rẹ̀: ṣugbọn Maria joko ninu ile.

Joh 11