Joh 10:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu da wọn lohùn wipe, Emi ti wi fun nyin, ẹnyin kò si gbagbọ́; iṣẹ ti emi nṣe li orukọ Baba mi, awọn ni njẹri mi.

Joh 10

Joh 10:18-27