Joel 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O ti pa àjara mi run, o si ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọtọ́ mi kuro, o ti bó o jalẹ, o si sọ ọ nù; awọn ẹ̀ka rẹ̀ li a si sọ di funfun.

Joel 1

Joel 1:4-10