Job 9:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, on kọja lọ li ẹ̀ba ọdọ mi, emi kò si ri i, o si kọja siwaju, bẹ̃li emi kò ri oju rẹ̀.

Job 9

Job 9:1-21