Job 4:19-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ambọtori awọn ti ngbe inu ile amọ̀, ẹniti ipilẹ wọn jasi erupẹ ti yio di rirun kòkoro.

20. A npa wọn run lati òwurọ di alẹ́, nwọn gbe lailai lairi ẹni kà a si.

21. A kò ha ke okùn iye wọn kuro bi? nwọn ku, ani lailọgbọn.

Job 4