Job 4:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBANA ni Elifasi, ara Tema, dahùn wipe,

2. Bi awa ba fi ẹnu le e, lati ba ọ sọrọ, iwọ o ha binujẹ? ṣugbọn tali o le pa ọ̀rọ mọ ẹnu laisọ?

3. Kiyesi i, iwọ sa ti kọ́ ọ̀pọ enia, iwọ sa ti mu ọwọ alailera le.

Job 4