Job 39:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IWỌ mọ̀ akoko igbati awọn ewurẹ ori apata ibimọ, iwọ si le ikiyesi igba ti abo-agbọnrin ibimọ?

2. Iwọ le ika iye oṣu ti nwọn npé, iwọ si mọ̀ àkoko igba ti nwọn ibi?

3. Nwọn tẹ ara wọn ba, nwọn bimọ wọn, nwọn si mu ikãnu wọn jade.

Job 39