Job 38:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBANA ni OLUWA da Jobu lohùn lati inu ìji ajayika wá o si wipe,

2. Tani eyi ti nfi ọ̀rọ aini igbiro ṣú ìmọ li òkunkun.

3. Di ẹgbẹ ara rẹ li amure bi ọkunrin nisisiyi, nitoripe emi o bère lọwọ rẹ ki o si da mi lohùn.

Job 38