Job 37:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AIYA si fò mi si eyi pẹlu, o si ṣi kuro ni ipò rẹ̀.

2. Fetisilẹ dãda, ki ẹ si gbọ́ iró ohùn rẹ̀, ati iró ti o ti ẹnu rẹ̀ jade wá.

3. O ṣe ilana rẹ̀ nisalẹ abẹ ọrun gbogbo, manamana rẹ̀ ni o si jọwọ rẹ̀ lọwọ de opin ilẹ aiye.

Job 37